Álífábẹ́ẹ́tì Yorùbá

Yorùbá Culture and Value

Our Publications

Tiwa ni Àṣà àti Ìṣe

Yorùbá Gbòde

Ilẹ̀ Yorùbá

Welcome to

Ẹgbẹ́ Onímọ̀-Èdè Yorùbá Nàìjíríà
(Yorùbá Studies Association of Nigeria)

Ẹgbẹ́ Onímọ̀-Èdè Yorùbá ti Nàìjíríà jẹ́ Ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga àti àwọn bọ̀rọ̀kìnní ọmọ orílẹ̀-èdè yìí tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí́ ìpolongo ìran Yorùbá àti Lítíréṣọ̀ rè. YSAN jẹ́ Ẹgbẹ́ tí ó ga jùlọ fún ìdàgbàsókè iṣẹ́ ìwádìí nínú ẹ̀kọ́ Yorùbá. Àwọn akadá àti àwọn olùfẹ́ èdè, lítíréṣọ̀ àti àṣà Yorùbá ni wọ́n dá Ẹgbẹ́ yìí sílẹ̀ ní ọdún 1970. Lára àwọn ènìyàn jàǹkàn-jàǹkàn tí wọ́n dá Ẹgbẹ́ yìí sílẹ̀ ni Ọ̀jọ̀gbọ́n àgbà Adébóyè Babalọlá, Olóògbé Afọlábí Ọlábímtán, Ayọ̀ Bámgbóṣé, Ọládélé Awóbùlúyì,̣ Ayọ̀ Bánjọ, Kújọọ́rẹ̀, Ọlátúndé Ọlátúnjí, Wándé Abímbọ́lá, Akínwùmí Ìṣọ̀lá, Sọpẹ́ Oyèláràn àti Alága... Read More

  1. Celebration of Yorùbá Icons

 

Click on Picture for more details!

Name 
The Association shall be called Ẹgbẹ́ Onímọ̀-Èdè Yorùbá Nàìjíríà (The Yoruba Studies Association of Nigeria).
Aims
The Aims of the Association shall be:
(a) To promote the academic development of Yoruba studies.
(b) To initiate, encourage and support scholarly research in Yoruba Studies.
(c) To promote and encourage the development of courses in Yoruba Studies at all levels of education in Nigeria and Overseas.
(d) To establish a learned journal of Yoruba Studies to be published regularly. (The aspiration of the Association is to publish the journal entirely in Yoruba, but it may initially be bilingual).
(e) To undertake such other activities as are consistent with the foregoing aims.