Celebration of Distinguished Yorùbá Icon

Akínwùmí Oròjídé-Ìṣọ̀lá

Professor Akinwunmi Isola (24 December 1939 – 17 February 2018) was a Nigerian playwright, novelist, actor, dramatist, culture activist and scholar. He was known for his writing in, and his work in promoting, the Yoruba language.

Early life and career

He was born in Ibadan in 1939, attended Labode Methodist School and Wesley College. He studied at the University of Ibadan, earning a B.A. in French. He earned an M.A. in Yoruba literature from the University of Lagos in 1978 before commencing academic work as a lecturer at Obafemi Awolowo University.

He was appointed Professor at the same University in 1991. Isola wrote his first play, Efunsetan Aniwura,[4] during 1961-62 while still a student at the University of Ibadan. This was followed by a novel, O Leku. In 1986, he wrote and composed the college anthem that is currently being sung in Wesley College Ibadan. He went on to write a number of plays and novels. He broke into broadcasting, creating a production company that has turned a number of his plays into television dramas and films. Though he claims that "my target audience are Yorubas", Isola has also written in English and translated to Yoruba.

On May 4, 2015, his book, Herbert Macaulay and the Spirit of Lagos was staged at University of Ilorin, Kwara state at the Performing Arts Theatre, it was directed by Adams Abdulfatai Ayomide, for the annual season of plays festival.

In 2000, in recognition of his immense contributions, he was awarded the National Merit Award and the Fellow of the Nigerian Academy of Letters. He was a visiting professor at the University of Georgia.[6]

Personal life

Akinwunmi Isola was married and had four children.

Death

Akinwunmi Isola died on 17 February 2018 in Ibadan, Oyo State, aged 78.

 

Oríkì Orílẹ̀ Ọ̀jọ̀gbọ́n Israel Bọ́dùnrìn Akínwùmí Oròjídé-Ìṣọ̀lá, NNOM, FNAL

Ọ̀jọ̀gbọ́n Israel Bọ́dùnrìn Akínwùmí Oròjídé-Ìṣọ̀lá

Ọmọ ayọ̀lápàtàpiti ìbọn

Ọmọ arógun-kún-n-kún-rojú

Ọmọ baba abẹsín-in-gbórí-ga-lójú-ogun.

Ọmọ oníkòkó àwọ́ọ̀wọ́tán

Ọmọ baba onígbàgbọ́ àràbà tó so Lábọ̀dé ró

Ọ̀jọ̀gbọ́n Akínwùmí Oròjídé-Ìṣọ̀lá

Ọkọ Adébọ́lá Àjokẹ́ Adéfún-n-kẹ́

Baba Akínjídé

Baba Olúwátóóyìn

Baba Olúwábùkọ́lá                  

Onínúure bí igbá ìwà.

Ìlọ̀kọ́ Arélù ni ọ́

Arélù ọmọ Ajọ́ba lólele

Tẹ̀ẹ̀tú kò jọ́ba lóhùn ẹ̀rọ̀

Ẹrúmọsá tíí jọ́ba lólele
Ọmọ akẹ̀tà lọ́na òsì

Ọmọ abẹ́nilórí-kú-kegé

Ọmọ abẹ́nilórí-fì-yòókù-jọba

Ọjọ́ kò tọ́jọ́, ọjọ́ kò tọ́jọ̀ lọ́jọ́ ọjọ́un àná

A n wẹ́ni rere ká fi jọba nílé onÍlọ̀kọ́ ọmọ Àrélù

Wọ́n ní kí ẹni rere jáde

Eni rere kọ̀ wọn kò jáde

Bẹ́ẹ̀ nidà Ìlọ̀kọ́ kọ̀, wọn kò wàkọ̀

Ọmọ abẹ́nilórí-kú-peregede

Agbedeméjì nÌlọ̀kọ́ ti í bẹ́ àna rẹ̀ lórí

Ọmọ abẹ́nilórí-tán fì-yòókù-jinni

Ọmọ agbẹ̀jẹ̀wẹ̀ lọ́rùn akáwọ                

Se bí ọmọ mẹ́ta nìyá yín bí

Ó bí Olúgbọ́n tó n gbọ́n eeni lọ níwájú ọba

Ó bí Arẹ̀sà Àjéjé tó n tulẹ̀ bọ̀ lẹ́yìn

Ìyá yín náà ló bí Onílọ̀kọ́ fúnra rẹ̀ tòhun tòpá lówó

Ọmọ alóhun-gbọọrọ tíí lé ohun gbọọrọ kánú oko

Ọmọ asẹ́ tíi mu ògì ní tútù

Ọmọ asẹ́ tí i mumi ní kíkan.

A lá a bẹ́lọ̀kọ́ lórí,

Onílọ̀kọ́ napá-nasẹ̀ sókè,

Ó ní sórí la ti í kú ni, àbẹ́sẹ̀?

Ọmọ abẹ́ni-lórí fìyòókù jọba

Ọ̀tún Ìlọ̀kọ́ ti múdà ó dèle

Òsì Ìlọ̀kọ́ ti múdà ó dẹ̀rọ̀

Agbedeméjì nìlọ̀kọ́ ti múdà bẹ́ àna rẹ̀ lórí

Ọmọ abẹ́nilórí-fìyókù jinni.

Jé kí n kì ọ́ lọ sílé ìyá rẹ

Èyin lọmọ aládé aládìkún

Ọmọ ọ̀bùn ìlẹ̀kẹ̀…

Ọmọ orí ni n ó wẹ̀ n ò wẹ ọsẹ

Ọmọ o ríwẹ̀ o kò wẹ̀

O ríwẹ̀, o kò wẹ ọsẹ.

Bàbá àwa ònkọ̀wé alátinúdá

Onínúure!

Ọ̀jọ̀gbọ́n Akínwùmí Ìṣọ̀lá, sùn-un-re o.

Our Heroes

Akínwùmí Oròjídé-Ìṣọ̀lá

Professor Akinwunmi Isola (24 December 1939 – 17 February 2018) was a Nigerian playwright, novelist, actor, dramatist, culture activist and scholar. He was known for his writing in, and his work in promoting,... Read More

 

 

 

 

Adébáyọ̀ Fálétí

(26 December 1921 – 23 July 2017) He was Africa's first newscaster, Africa's first stage play Director, Africa's first film editor and librarian with the first television station in Africa (WNTV/WNBS), Nigeria's first Yoruba presenter on... Read More

 

 

 

 

D.O. Fágúnwà

Daniel Olorunfẹmi Fagunwa MBE (1903 – 9 December 1963), popularly known as D. O. Fagunwa, was a Nigerian author who pioneered the Yoruba-language novel. He was born in Oke-Igbo, Ondo State.... Read More

 

 

 

 

Babs Fáfunwá

Aliu Babatunde Fafunwa (23 September 1923 – 11 October 2010)[1] was a Nigerian educationist, scholar and former minister for Education. As minister, he was in charge of the biggest school... Read More

 

 

 

 

Member Login

Membership Sign Up